Farouk m Lèmmù (Live|Explicit)-文本歌词

Farouk m Lèmmù (Live|Explicit)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Alhaja! Amuda mi Yusufu ọmọ Fashola Gbogbo yín ẹ kú ọdún Ojú gbogbo wa ló pé síbí yìí lọ́dún yìí once again Àwọn General General gbogbo wọn ni wọ́n ń bẹ níkàlẹ̀ Àwọn ọ̀gá lójú ogún o ọ̀gá lójú ogun Àwọn Captain ní industry tó lówó lórí gbogbo wọn ni wọ́n ń bẹ níkàlẹ̀ t’a wá jó’jó ọdún Ọlọ́hun Ọba o ṣé ti dídá tó o dá wa sí àánú Olọ́hun lórí wa Ẹ ẹ̀ dẹ̀ ní dọ̀lárẹ̀yìn mo kí i yín Ah! Ayome ọmọ Odùtọ́lá ọmọ Gbélébùwà níjẹ̀bú Òde Farouk mi (Farouk mi) Ọmọ lèmọ́mù Farouk (Farouk mi) Farouk ọmọ Wasilatu (Farouk mi) Yí ó da fún ọ tí ó pọ̀ (Farouk mi) Yí ó da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (Farouk mi) Polanco o ò gbọ́’hun tí kò ń sọ (Adé orí ọ̀kín) Ẹlẹlẹ Maiko o ò gbóhun tí mò ń sọ o (Adé orí ọ̀kín) #INSTRUMENTAL Àrẹ̀mọ Adétóṣe o ọmọ Fágbèmí Bámbọ̀ láti Chicago ,Abdulwazir gbogbo yín ni mo kí K1 De Ultimate Arábámbí Wọ́n á wọ́n sóko bí èrè ni o o o o Ẹ̀yin mọdé wọ̀nyí mò ń ka tira orin mi lọ́wọ Ẹ máa bá n ṣé ní ṣísẹ̀ntẹ̀lé Torí Fújì mi (Fújì mi) #INSTRUMENTAL Àlùjó Fújì (Fújì mi) Àlùjó inú ẹ̀ ó pọ o (Fújì mi) Tiwa làlùjó Fújì (Fújì mi) O ò gbọ́’hun tí mò ń sọ o (Adé orí ọ̀kín) Èjìrẹ́, ẹ ẹ̀ gbọ́’hun tí mò ń sọ o (Adé orí ọ̀kín) Ló bá ti lẹ̀kùn mọ́ wọn (ó fi kọ́kọ́rọ́ pamọ́) Ó tìlẹ̀kùn mọ́ wọn (ó fi kọ́kọ́rọ́ pamọ́) Ó ní níbo lẹ̀ ń lọ (ó fi kọ́kọ́rọ́ pamọ́) Ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Ọmọ Kọ́lá Balógun ó wá láti Canada (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Olúpo wá láti Canada (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Èjìrẹ́ Olúpo (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Àlàelú yí ọ́ da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Yàkoyó, o ò gbọ́’hun tí mò ń sọ o (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) O ò gbọ́’hun tí mò ń sọ o (ṣé ẹ̀ ń r’Áyìndé) Ọkọ ìlú òṣì kan ò mà ní ẹ ẹ́ ta (Adé orí ọ̀kín) Ìyà kan ò mà ní ẹ ẹ́ jẹ (Adé orí ọ̀kín) Ah ah ah ọmọdé yìí, kí lò ń ṣe fún mi (Adé orí ọ̀kín) Ẹ bá mi b’ọmọdé yìí Ṣé ó fẹ́ pamí ni? (Adé orí ọ̀kín) Ijó ni ẹ bá mi jó (ijó ni ẹ bá mi jó) Ijó ni ẹ bá mi jó o(Ijó ni ẹ bá mi jó) Ijó ni ẹ bá mi jó o(Ijó ni ẹ bá mi jó) Ẹni tó bá ṣe ṣíọ̀ ẹ Àyìndé o (Olúwa á ṣe ṣíọ̀ wọn nígbà bíi million) Kí lẹ tíì rí o (Ẹ̀yin ará mi, kàsàkàsà ń bọ̀ bàbá késekése) Bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó sẹ́ (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ẹ̀gbẹ́ jo) Seruti, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó sẹ́ (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ìbàdí jo) Jaccuzi, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ẹ̀gbẹ́ jo) Nigga, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó sẹ́ (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ìbàdí jo) Ẹbí aláṣọ, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ẹ̀gbẹ́ jo) Mr Folly, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ìbàdí jo) Mudi, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ẹ̀gbẹ́ jo) Bayshe, bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ìbàdí jo) Al-Akeem, ọmọ olókè bó ti ṣe wù ẹ́ lo le jó (Bó jẹ́ ko ko láti Ìsàlẹ̀, o sì le f’ẹ̀gbẹ́ jo) Ah ta wá lẹni tó lè ṣe (ìwọ ni ìwọ ni) Ta l’ẹni tó le ṣé o (ìwọ ni ìwọ ni) Ta wá lẹni tó lè ṣe (ìwọ ni ìwọ ni) Ta l’ẹni tó le ṣé o (ìwọ ni ìwọ ni) Thank you God (ìwọ ni ìwọ ni) Thank you God (ìwọ ni ìwọ ni) Mi ò r’ẹ́ni tó le ṣé (ìwọ ni ìwọ ni) Kó dàbí Elédùmarè (ìwọ ni ìwọ ni) Mo kọrin Àyìndé Adéwálé Olúayé kọ́rọ̀ náà dé Ọba Fújì Àyìndé Baby bọ̀bọ́ ẹ wá gbọ́ Ọ̀rọ̀ tó wà nílẹ̀ yìí, é le bọ̀jẹ́ o Àyìndé Àwọn tí ò dẹ̀ mọ bí a ti ṣe ń ṣe o (kí wọ́n lọ lẹ̀, kí wọ́n lọ sẹ́ḿpẹ́) Àwọn tí ò dẹ̀ mọ bí a ti ṣe ń ṣe o (kí wọ́n lọ lẹ̀, kí wọ́n lọ sẹ́ḿpẹ́) Ijó yẹn nìyẹn (ohùn yẹn nìyẹn) #INSTRUMENTAL Fẹ́mi Marshal, ijó yẹn nìyẹn ohùn yẹn nìyẹn Àwọn tí ò dẹ̀ mọ̀ bí a ti ṣe ń ṣe o (kí wọ́n lọ lẹ̀, kí wọ́n lọ sẹ́ḿpẹ́) Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Òkété, Òkété ò bẹ́gijà mọ́ o yíyọ́ lẹkùn ń yọ (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Òkété, Òkété ò bẹ́gijà mọ́ kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá) Máa gbọ́ bí mo ṣe ń wí Ọlámilékan ọmọ Adébarí Ṣé ò ń bá mi tọ́jú National President Worldwide Ẹnu ọyàn Bíléwú ní New York City mo kí ẹ kí ẹ Olórí gbogbo Ẹgbẹ́ K1 Fans Club worldwide Káàbọ̀ sí Nàìjíríà gbogbo yín ni mo kí Olórí gbogbo K1 Fans Club worldwide ọmọ Bíléwú Káàbọ̀ sí Nàìjíríà mo kí ẹ kí ẹ ọmọ Bíléwú Lórúkọ gbogbo Ẹgbẹ́ ẹgbẹ́ mi pátápátá K1 fans club world over gbogbo yín la kí Láti Nàìjíríà tó fi dé ìlú London kárí àgbáyé Worldwide President máa wolẹ̀ máa ràba Bíléwú Òun l’olórí ẹgbẹ́ wa ọmọ Bíléwú Èèyàn K1 De Ultimate ni O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn o Bàbá àgbà pátápátá mo gba ara tì ẹ mo kí gbogbo executive Àyìndé adé mi ẹ ṣeun mi Ẹ kú àdúrótì ọmọ t’Anífowóṣe Bíléwú, kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o, kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o, kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Òkété Òkété Òkété Òkété Òkété ò bẹ́gìjà mọ́ o yíyọ́ lẹkùn ń yọ́ (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Òkété, Òkété ò bẹ́gijà mọ́ o kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá) Bisi baby Mo ní yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ́ Tutu, Doki Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o, kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Òkété Òkété ò bẹ́gìjà mọ́ o yíyọ́ lẹkùn ń yọ́ (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ, yíyọ́ lẹkùn ń yọ) (Òkété, Òkété ò bẹ́gijà mọ́ o kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá) Ìran òkété ò bẹ́gìjà mọ́ o (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ́) Dr Sam, Òkété ò bẹ́gìjà mọ́ (Kí wọ́n má f’ẹ kù w’ájá) Òkété ò bẹ́gìjà mọ́ o (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ́) Òkété ò bẹ́ gìjà mọ́ (Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá) Bíléwú, Òkété ò bẹ́ gìjà mọ́ (Yíyọ́ lẹkùn ń yọ́) Bísí, Òkété ò bẹ́ gìjà mọ́ (Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá) Òkété òkété òkété Kafayatu ọmọ Aṣòóbiníjà mo kí ẹ kí ẹ Kafaya Tutu, Tútù kan Boston kan Káàbọ̀ sí Nàìjíríà o Kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá o, kí wọ́n má f’ẹkùn w’ájá Shodi Ọbá ti dé, adúpẹ́ Ọlọ́hun arábámbí Àdúrà wa ti gbà o Orílé Agége Wasiu Àyìndé O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Dr Sam gbogbo New York City Ṣé ẹ bá mi kí gbogbo ilé Àjọṣe wa ò ní bàjẹ́ lọ́lá Ọlọ́hun Ọba Ọlámilékan ọmọ Bíléwú Ẹnu ọyàn! Ọyàn! Ẹ̀yin tèmi ọmọ America o Baby mi ọmọ Canada o Àti ẹ̀yin ti Nàìjíríà (ẹ ma fẹ̀sọ̀ jayé o) Bí kókó fẹ́ni lẹ́sẹ̀ (A kìí j’orí ìmàdò) Siro, b’a dẹ̀ tún j’orí ìmàdò (Àjọ kùmọ̀ la ò ní dé) B’a bá dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni) B’a bá sì dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni) Bí kókó fẹ́ni lẹ́sẹ̀ (A kìí j’orí ìmàdò) Al - Akeem bí kókó fẹ́ni lẹ́sẹ̀ (A kìí j’orí ìmàdò) Dr Sam b’a dẹ̀ tún j’orí ìmàdò (Àjọ kùmọ̀ la ò ní dé) B’a bá dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni) B’a bá sì dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni) B’a bá dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni) Ah B’a bá sì dájọ́ kùmọ̀ (Ká ya mọ̀’wọ̀n ara ẹni)