Obeki gbogbo Dubai Ijó ni o bá mi jó (ijó ni o bá mi jó) Ìwo tó ò bá sí nínú squad mi Gbéra Àyìndé Ọmọ́gbọ́láhàn arábámbí Alápa yẹbẹuẹbẹ níbo lẹ̀ ń lọ? (Ajùdí yàbàyàbà níbo lẹ mí rè) Mo kí gbogbo yín ẹ kú ọdún O ṣé modúpẹ́ Lamborghini mo dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹ o ṣeun Olúayé Fúji (Ọ̀gá wa o) Akin ìlú Ijó ọdún là ń jó Gẹ́gẹ́ bí àyò mi, etí inú Mustapha SEGO ko yámi létí Ìwọ tó ò bá sí nínú wa fara ẹ balẹ̀ Àyìndé mi Wasiu Ẹnu mi gbọ̀rọ̀ Arábámbí Èmi l’olórí ilé, èmi l’olórí ilé K1 De Ultimate Kí la fi ilé mú team Lagos ló ìdílé mú Gbogbo àwọn General mi Gbogbo wọn ni wọ́n kalẹ̀ ni wọ́n dúró Kòsí nǹkankan ka máa ṣe fàájì ara wa Hoi, hoi, hoi Oṣé! oṣé! Mustapha mi SEGO Adékúnlé Ìwọ l’alága èkó Ìlù ò ní tóbi kó kéré k’ápá òrò kó má mà ka o Walimustapha SEGO K’Áyìndé Musiliu Ayédáadé tó jẹ́ National President National Union Ẹnu mi gbàá, èmi ni mo gbàá K1 De Ultimate K1 De Ultimate Arábámbí Àyìndé Wasiu, ibi téèyàn bá ṣe sí ló ti ń jẹ Ọ̀rọ̀ òṣèlú tó wà nílẹ̀ arábámbí Ìgbà tí a wà ní opposition, tí wọ́n ń fojú wa rí réderéde Àyìndé o Hoi! Ìgbà tí wọ́n ń fojú gbogbo wa rí réderéde, tí gbogbo wa ń jìṣẹ́ jìyà Àkànbí Aṣíwájú A fi team Lagos lélẹ̀ ọmọ anífowóse one love Abẹ́ àsìá ẹ ní everybody wa dúró sí A ò dẹ̀ ní yẹ̀ níbẹ̀ títí láéláé Bẹ́ẹ̀ ni ó máa rí lọ́lá Ọlọ́hun àmín o Èèyàn tí ò bá mọ̀ ẹ́, ẹ má f’ẹnu bàwá jẹ́ Èmi ni alátùn-úntò tó ń to gbogbo ilé Arábámbí, olórí oko bambam fún gbogbo team Lagos ọmọ t’Anífowóṣe SEGO ìwọ àti Àyìndé Musiliu Ayédáadé Agarau ago Ìsàlẹ̀ ìgángan area o Ọkọ ìlú, ọkọ ìlú Baálẹ̀.. etí SEGO mi (SEGO MI) Ìwọ àti Àyìndé mi Musiliu (Ayédáadé) Ẹ̀yin lẹ kó’lé dání Mustapha (musitapha) Mustapha mi SEGO (musitapha) Area mi ni Ìsàlẹ̀ Ìganngàn area (musitapha) Ìwọ àti Àyìndé mi Musiliu (egúngún Ayédáadé) Ẹ̀yin méjèèjì ọwọ́ yín nílùú wà (musitapha) Ẹ̀yin méjèèjì to ọwọ́ ọ yín nnìlú wà (egúngún ayédáadé) Èkó ni mo fi ẹ́ sí Ìjọba t’Èkó lọ́wọ́ ẹ ló wà Musitapha Àyìndé mi National President Torí Aṣíwájú la fi mú’lé dání ìgbà tí’yà ń jẹ wá T’a wà l’opposition Àyìndé Tí wọ́n ń kó wa kiri Tí wọ́n ń lù wá kiri baálẹ̀ ọkọ ìlú Àtìmọ́lé ojoojúmọ́ Olúayé onífújì ta lẹni tá a rí? A à rí ẹnìkan Nǹkan náà wá da tán Ọbẹ̀ náà wá jóná tán owó náà wá dé tán K1 De Ultimate Àyìndé ol*** ńlá tó fi bí’gba ọmọ Ẹ má sọ̀rọ̀ yìí di comedy mọ́ mi lọ́wọ́ Arábámbí Àyìndé o Olúayé ibà arábámbí ọkùnrin ogun o (Àyìndé o Olúayé ibà arábámbí ọkùnrin ogun)